Mo Ń Wo Ọ

(Saturday, 7th March 2026)

[Chorus]
Mo ń wo Ọ o, Olúwa mi, Ọlọ́run mi,
Mo ń wo Ọ, o Ìwọ ni Ọlọ́run mi,
Omi i ba ti gbé mi lọ,
Ṣùgbọ́n O fi 'fe gbà mí là,
Olúwa mi, èmi yóò máa woo Ọ.


[Verse 1]
Olúwa, gbé mi, gbé mi sókè kí n lè fò,
Mi ò lè da nìkan rin ninú ayè,
Ìrìn àjò ayé yìí kò rọrùn láìsí Ọ l' ẹ̀gbẹ́ mi,
Olúwa àt'Ọlọ́run mi, mo ń wo Ọ.

[Chorus]
Mo ń wo Ọ, o Olúwa mi, Ọlọ́run mi,
Mo ń wo Ọ, o Ìwọ ni Ọlọ́run mi,
Omi i ba ti gbé mi lọ,
Ṣùgbọ́n, O fi 'fe gbà mí là,
Olúwa mi, èmi yóò máa woo Ọ.


[Verse 2]
Ọ̀tá pọ̀ jù ní 'bi gbogbo nínú ayè,
Wọ́n lá ẹ̀nú wọn láti gba ẹ̀mí mì,
Wọ́n ńgbàdúrà l'ọ̀sán l'òru kí n lè ṣubú ṣùgbọ́n mo mọ̀,
Wípé Iwọ lole ṣẹ́gun fún mi.

[Chorus]
Mo ń wo Ọ, o Olúwa mi, Ọlọ́run mi,
Mo ń wo Ọ, o Ìwọ ni Ọlọ́run mi,
Omi i ba ti gbé mi lọ,
Ṣùgbọ́n, O fi 'fe gbà mí là,
Olúwa mi, èmi yóò máa woo Ọ.


[Verse 3]
L' ọ̀pọ̀ ìgbà mo rò pe O ko sí níbẹ̀,
Bi O ṣe kẹ̀yìn s'Ọmọ Rẹ l'órí igì,
Nígbà t'Ó wà lórí àgbélébùú nítorí p' O pinnu,
Láti rà wá padà nínú ẹ̀ṣẹ̀.

[Chorus]
Mo ń wo Ọ, o Olúwa mi, Ọlọ́run mi,
Mo ń wo Ọ, o Ìwọ ni Ọlọ́run mi,
Omi i ba ti gbé mi lọ,
Ṣùgbọ́n, O fi 'fe gbà mí là,
Olúwa mi, èmi yóò máa woo Ọ.


[Verse 4]
O fún mi ní ọ̀rọ̀ Rẹ́ f' awọn ọmọ Rẹ̀,
Kí n'bá Ọ rin nínú írìn àt' íṣè,
Láti yí ọkàn àwọn ọmọ Rẹ padà s' ọ́dọ̀ Rẹ,
Nítorí Ìwọ nìkan ni ìrètí wọ̀n.

[Chorus]
Mo ń wo Ọ, o Olúwa mi, Ọlọ́run mi,
Mo ń wo Ọ, o Ìwọ ni Ọlọ́run mi,
Omi i ba ti gbé mi lọ,
Ṣùgbọ́n, O fi 'fe gbà mí là,
Olúwa mi, èmi yóò máa woo Ọ.

[Final Chorus]
Mo ń wo Ọ, o Olúwa mi, Ọlọ́run mi,
Mo ń wo Ọ, o Ìwọ ni Ọlọ́run mi,
Omi i ba ti gbé mi lọ,
Ṣùgbọ́n, O fi 'fe gbà mí là,
Olúwa mi, èmi yóò máa woo Ọ.

Share this Page!

"Seek the Lord while He may be found; call upon Him while He is near. Let the wicked forsake his way, and the unrighteous man his thoughts; let him return to the Lord, and He will have mercy on him; and to our God, for He will abundantly pardon." Isaiah 55:6-7

Contact Info

+44 7405 436304
+234 90 7937 4685

If a man breathes his last breath, his Spirit departs and continues his life elsewhere. Whatever life he lives here will determine his destination and what his next life will be like.

@pastorjesudairo

App Downloads

You can download our apps below



© Copyright 2026 Jesudairo - The Word Of God - Proclaiming the word of God -  All Rights Reserved